Ìtàn Jòsáyà: Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà; Kórìíra Ohun Búburú—Apá Kìíní
Inú ìlú tí wọ́n ti pa Jèhófà tì ní Jòsáyà dàgbà sí, èyí tó pọ̀ jù lára àwọn ìlú náà ló sì ń sin Báálì. Ṣé tiẹ̀ máa wá dá yàtọ̀ ni, ṣé á lè dúró lórí ìpinnu ẹ̀ láti ṣé ohun tó tọ́?