Ìtàn Jòsáyà: Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà; Kórìíra Ohun Búburú

Ìfẹ́ tí Ọba Jòsáyà ní sí Jèhófà Ọlọ́run mú kó pinnu pé òun máa pa àwọn abọ̀rìṣà run pátápátá kúrò nílùú. Ṣé ó máa ṣàṣeyọrí pẹ̀lú bí wọ́n ṣe ń halẹ̀ mọ́ ọn, tí wọ́n sì ń ta kò ó?

Ìtàn Jòsáyà: Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà; Kórìíra Ohun Búburú​—Apá Kìíní

Àárín àwọn tó ń sin Báálì ni Jòsáyà dàgbà sí. Ṣé Jòsáyà máa lè ṣe ohun tó tọ́ lójú Jèhófà?

Ìtàn Jòsáyà: Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà; Kórìíra Ohun Búburú​—Apá Kejì

Ọba Jòsáyà pinnu láti mú ìbọ̀rìṣà kúrò nílùú pátápátá, kó tún ran àwọn aráàlú lọ́wọ́ láti nífẹ̀ẹ́ Jèhófà kí wọ́n sì máa ṣé ohun tó tọ́. Ṣé ó máa ṣàṣeyọrí?