Abala 1: Ìmọ́lẹ̀ Tòótọ́ fún Aráyé
Abala 1: Ìmọ́lẹ̀ Tòótọ́ fún Aráyé
Àwọn ohun àgbàyanu tó ṣẹlẹ̀ kí Mèsáyà tó dé.
Àwọn Àkòrí Tó Jọ Ọ́
JésùO Tún Lè Wo
ÀLÀYÉ ÀWỌN ẸSẸ BÍBÉLÌ
Àlàyé Jòhánù 1:1—“Ní Ìbẹ̀rẹ̀, Ọ̀rọ̀ náà Wà”
Ẹsẹ Bíbélì yìí jẹ́ ká mọ irú ẹni tí Jésù Kristi jẹ́ kó tó wá sáyé.
OHUN TÍ BÍBÉLÌ SỌ
Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Màríà Wúńdíá?
Àwọn kan sọ pé wúńdíá tó bí Jésù kì í ṣe ẹlẹ́ṣẹ̀. Ṣé Bíbélì jẹ́rìí sí i pé bẹ́ẹ̀ ló rí?
TẸ̀ LÉ ÀPẸẸRẸ ÌGBÀGBỌ́ WỌN
Màríà —“Wò Ó! Ẹrúbìnrin Jèhófà!”
Kí ni ìdáhùn tí Màríà fún Gébúrẹ́lì fi hàn nípa irú ìgbàgbọ́ tó ní? Àwọn ànímọ́ pàtàkì míì wo ló tún fi hàn?
OHUN TÍ BÍBÉLÌ SỌ
Àwọn Wo Ni “Amòye Mẹ́ta Náà”? Ṣé “Ìràwọ̀” Bẹ́tílẹ́hẹ́mù Ni Wọ́n Tẹ̀ Lé?
Ọ̀pọ̀ àwọn ọ̀rọ̀ tó gbajúmọ̀ tí wọ́n máa ń sọ nígbà Kérésìmesì ni kò sí nínú Bíbélì.
TẸ̀ LÉ ÀPẸẸRẸ ÌGBÀGBỌ́ WỌN
Jósẹ́fù Dáàbò Bo Ìdílé Rẹ̀, Ó Pèsè fún Wọn, Ó sì Ní Ìfaradà
Báwo ni Jósẹ́fù ṣe dáàbò bo ìdílé rẹ̀? Kí nìdí tó fi ní láti kó Màríà àti Jésù lọ sí Íjíbítì?
ÌHÌN RERE LÁTỌ̀DỌ̀ JÉSÙ
Abala 1: Ìmọ́lẹ̀ Tòótọ́ fún Aráyé
Yorùbá
Abala 1: Ìmọ́lẹ̀ Tòótọ́ fún Aráyé
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1112023101/univ/art/1112023101_univ_sqr_xl.jpg