Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Dáníẹ́lì Nígbàgbọ́ Jálẹ̀ Ìgbésí Ayé Rẹ̀—Apá Kìíní

Dáníẹ́lì Nígbàgbọ́ Jálẹ̀ Ìgbésí Ayé Rẹ̀—Apá Kìíní

Dáníẹ́lì kojú ọ̀pọ̀ ìṣòro tó lè mú kó fi ìjọsìn tòótọ́ sílẹ̀, síbẹ̀ ó ṣe gbogbo ohun tó lè ṣe kó lè ní ìgbàgbọ́ tó lágbára nínú Jèhófà.