Ìsọfúnni Ṣókí—Bolivia
- 12,152,000—Iye àwọn èèyàn
- 29,440—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
- 452—Iye àwọn ìjọ
- 419—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún
ÌRÒYÌN
Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Gba Àmì Ẹ̀yẹ Torí Bí Wọ́n Ṣe Gbé Àṣà Ìbílẹ̀ Bòlífíà Yọ Níbi Àpéjọ Àgbègbè Wọn
Wọ́n fún àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà lámì ẹ̀yẹ torí àtúnṣe ńlá tí wọ́n ṣe síbi tí wọ́n ti ṣe àpéjọ náà, tí wọ́n sì pàtẹ àwọn ohun tó jẹ mọ́ àṣà ìbílẹ̀ àwọn ọmọ ilẹ̀ Bòlífíà.