Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

DI Ọ̀RẸ́ JÈHÓFÀ

Ọlọ́run Ń Mú Kó Dàgbà

Ọlọ́run Ń Mú Kó Dàgbà

Ṣé o mọ bí òtítọ́ ṣe ń dàgbà nínú ọkàn àwọn èèyàn?

Ẹ̀yin òbí, ẹ ka 1 Kọ́ríńtì 3:6, 7, kẹ́ ẹ sì jíròrò ẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọmọ yín.

Wa eré yìí jáde, kó o sì tẹ̀ ẹ́ sórí ìwé.

Lẹ́yìn tẹ́ ẹ bá wo fídíò Ọlọ́run Ń Mú Kó Dàgbà, ran ọmọ ẹ lọ́wọ́ láti kun àwọn àwòrán tó bá nọ́ńbà kọ̀ọ̀kan mu. Bẹ́ ẹ ṣe jọ ń ṣe é, ẹ jọ máa sọ̀rọ̀ nípa ìdáhùn ìbéèrè tó wà nísàlẹ̀.