November 20-26
MÍKÀ 1-7
Orin 26 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Kí Ni Jèhófà Ń Béèrè Lọ́wọ́ Wa?”: (10 min.)
[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Míkà.]
Mik 6:6, 7—Tí a kò bá hùwà tó dáa sí àwọn èèyàn, Jèhófà kò ní tẹ́wọ́ gba àwọn ẹbọ wa (w08 5/15 6 ¶20)
Mik 6:8—Àwọn ohun tí Jèhófà ń béèrè lọ́wọ́ wa kò ju agbára wa lọ (w12 11/1 22 ¶4-7)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Mik 2:12—Báwo ni àsọtẹ́lẹ̀ yìí ṣe ṣẹ? (w07 11/1 15 ¶6)
Mik 7:7—Kí nìdí tó fi yẹ ká “fi ẹ̀mí ìdúródeni hàn” sí Jèhófà? (w03 8/15 24 ¶20)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Mik 4:1-10
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sm 83:18—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni—Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ẹk 3:14—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni. Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh 123-124 ¶20-21.
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Orin 106
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (6 min.)
Jèhófà Fẹ́ Ká Jẹ́ Ọ̀làwọ́ (Òwe 3:27): (9 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò yìí.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 21 ¶15-20, àtẹ ìsọfúnni “Àwọn Ohun Tí Yóò Ṣẹlẹ̀ Lọ́jọ́ Iwájú,” àpótí tó wà fún àtúnyẹ̀wò “Ṣé O Gbà Lóòótọ́ Pé Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso?”
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 132 àti Àdúrà