Privacy Settings

To provide you with the best possible experience, we use cookies and similar technologies. Some cookies are necessary to make our website work and cannot be refused. You can accept or decline the use of additional cookies, which we use only to improve your experience. None of this data will ever be sold or used for marketing. To learn more, read the Global Policy on Use of Cookies and Similar Technologies. You can customize your settings at any time by going to Privacy Settings.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Dáfídì Fi Ìfẹ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Hàn

Dáfídì Fi Ìfẹ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Hàn

Dáfídì wá ẹni tó lè fìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn sí nínú ilé Sọ́ọ̀lù (2Sa 9:1; w06 6/15 14 ¶6)

Dáfídì gbé ìgbésẹ̀ láti ran Mefibóṣétì lọ́wọ́ láìjáfara (1Sa 20:15, 42; 2Sa 9:5-7; w05 5/15 17 ¶12)

Dáfídì ní kí Síbà máa bójú tó ogún Mefibóṣétì (2Sa 9:9, 10; w02 2/15 14 ¶10)

Arábìnrin àgbàlagbà kan ń gbá arábìnrin ọ̀dọ́ kan mọ́ra, ó sì ń tù ú nínú.

Dáfídì ò gbàgbé ìlérí tó ṣe fún Jónátánì. Ó yẹ káwa náà máa fìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn sáwọn ará wa.​—Sm 41:1, 2; Owe 19:17.