ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Ámínónì Mọ Tara Ẹ̀ Nìkan, Ìyẹn sì Yọrí sí Àdánù Ńlá
Ọkàn Ámínónì fà sí Támárì (2Sa 13:1, 2; it-1 32)
Ámínónì fipá bá Támárì sùn (2Sa 13:10-15; w17.09 5 ¶11)
Ábúsálómù pa Ámínónì (2Sa 13:28, 29; it-1 33 ¶1)
Kí làwọn tó ń fẹ́ ara wọn sọ́nà lè ṣe tí wọn ò fi ní ṣèṣekúṣe? Wọ́n gbọ́dọ̀ máa kó ara wọn níjàánu, kí wọ́n sì yẹra fáwọn ipò tó lè mú kí wọ́n ṣèṣekúṣe.