Ẹ̀KỌ́ 10

Yí Ohùn Pa Dà Bó Ṣe Yẹ

Yí Ohùn Pa Dà Bó Ṣe Yẹ

Àǹfààní wo ló máa ṣe àwọn tó ò ń bá sọ̀rọ̀ tó o bá yí ohùn àti ìró pa dà bó ṣe yẹ, tó o sì yí bó o ṣe ń yára sọ̀rọ̀ pa dà?