Atọ́ka
Àwọn atọ́ka yìí máa jẹ́ kó o rí ìsọfúnni tó ò ń wá nínú àwọn ìwé wa. Nínú ìwé Publications Index, wàá rí àwọn àkòrí tá a ti sọ̀rọ̀ nípa ẹ̀ àtàwọn ẹsẹ Bíbélì tá a ti ṣàlàyé níbẹ̀. Irú ìsọfúnni kan náà ló wà nínú Ìwé Ìwádìí fún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà, àmọ́ kò kún tó ti Publications Index. Àwọn ìwé méjèèjì yìí wà lórí ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ (ìyẹn Watchtower ONLINE LIBRARY). A tún láwọn fídíò kan tá a tò lẹ́sẹẹsẹ tó máa jẹ́ kó o túbọ̀ gbádùn ìdákẹ́kọ̀ọ́ ẹ.

