Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Ìgbéyàwó àti Ìdílé

Bíbélì tó jẹ́ ìwé tó wà fún gbogbo èèyàn sọ ohun tó o lè ṣe kó o lè túbọ̀ gbádùn ìgbéyàwó rẹ, ó sì sọ ohun tó máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti tọ́ àwọn ọmọ rẹ. *

^ Orúkọ àwọn kan tí a fà yọ ní apá yìí ti yí pa dà.

ÌGBÉYÀWÓ ÀTI ÌDÍLÉ

Bí Òbí Ṣe Lè Tọ́ Ọmọ Sọ́nà

Kí nìdí tó fi máa ń rọrùn fáwọn ọmọdé láti ní àjọṣe tó lágbára pẹ̀lú àwọn ojúgbà wọn, tí wọ́n ò sì ní ká ìtọ́sọ́nà àwọn òbí wọn sí?

ÌGBÉYÀWÓ ÀTI ÌDÍLÉ

Bí Òbí Ṣe Lè Tọ́ Ọmọ Sọ́nà

Kí nìdí tó fi máa ń rọrùn fáwọn ọmọdé láti ní àjọṣe tó lágbára pẹ̀lú àwọn ojúgbà wọn, tí wọ́n ò sì ní ká ìtọ́sọ́nà àwọn òbí wọn sí?

Ìgbéyàwó

Ọmọ Títọ́

Ìtẹ̀jáde

Ìdílé Rẹ Lè Jẹ́ Aláyọ̀

O lè ní ìgbeyàwó àti ìdílé tó láyọ̀ tó o bá ń fi àwọn ìlànà Bíbélì sílò.